Yoruba dun pupo
Yoruba lewa pupo
Yoruba ti niyi to
Yoruba ma lewa o
Kimi loriki mi
ni ede geesi...
Momo pe ko se e se
YOruba naa loto se e
Ifetayo, omo Elese
Omo Ajiboro
Omo Idagedegudu
Omo Oniwo kuloyegbe
Omo kanran kanran
bi oko titun
Omokuku dami agbada nu
nu lore
Ojo setan kotun romo
gbogbo ayaba sunkun
lole baba won
Ati pa yoruba ti
aaa, omase o
A o mo iyi oun ti ani
ntori asa alasa
Se tin ba wa gbera so
ti moni un o gbee laruge
wa poju ni?
Abi tinba wa di ogbontarigi
akowe Yoruba buru ni?
Mo se tan lati se bi
Omowe Daniel Fagunwa,
Akinwunmi Isola,
Amos Tutuola,
Olabimtan Afolabi,
Adebayo Faleti
ati beebe lo
Oun ani langbe
laruge....
Yoruba, titemi ni
Un o gbe o laruge
Un o fi o yangan
Ntori odara
Oosi lewa
lopolopo
Tayo,
ReplyDeleteLet's work together. I like this! You dazzle me greatly
Wow! Im in love with ur works too
ReplyDeleteHi. You have an award to pick up on my blog :)
ReplyDeleteOh,thanks
ReplyDeleteI like this Yoruba poem. It reads so good.
ReplyDeletewww.josephomotayo.blogspot.com/2013/03/saraba-13-africa-issue.html?m=1
This is orisun.u av don a great job here.i am proud to b a yoruba
ReplyDeleteI wish I could understand yoruba enough to decipher the content of this poem, but in that regard I remain a failed Lagosian but writing in ones language leaves a beauty and an enigmatic quality to the reader..though I could not decipher it,it is no doubt beautiful to my sight
ReplyDelete